Page text
=
Ipinle lwo-Orun N igeria
= 9
o3
> © i!
| (
AN :
I| \) a
i
af
as
co
“O°.d
O) -Q
0,2 niNo text on this page.
Inu ile ni ohun pataki ti a fi nse ord ni ilu yi wa.
Ki ilu yi ba le ni owo si i ati ki enia ba le gbadun
aiye si i ohun dgbin fun lilo ti ara wa ati fun tita
ni ilu okére ni lati dara si i. Nitorina, a nilati sa
gbogbo agbara wa lati tun eto ise égbin wa se.
A se iwe yi pataki fun awon-agbe, o si fi awon ohun
ti Ijoba nse han lati ran yin lowo lati le ni ohun
dgbin ti o dara, sugbon die ni Ijoba le se tika-raré,
0 nfe isowopo nyin ati ti gbogbo awon agbe miran
pelu ti a ba nfe ki nkan yipada si rere.
Mo ni ireti pe iwe yi yio jeki e mo riri ise ti Ijoba
nse ki e ba le mura lati se ipin-ise nyin. Awa yio
wa le jumo sise po fun igba ti o dara fun gbogbo enia.
kn
Alakoso Ise Agbe ati awon alumoni inu ile ti
Ipinle Iwo-Orun i‘Ogbin Daradara
Fun Igbadun Daradara
Ijoba Ipinle lwo-Orun lo se iwe yi
lle-ise Isotype Institute Ltd.
lo se eto ré ni 1955Ninu ile ni pupo ninu oro ile lwo-Orun ti nwa;
gegebi eyin, ekure ati epo, orombo,
agbado, gbaguda, epa, isu, eran gsin, etc.
Die ninu awon ohun eso Ile Iwo-Orun ni nwon nfe ni
gbogbo agbaiye:
owd, ewe taba, etc.Bi awon agbe ba ti ri nkan ogbin si, béni nwon yio ri nkan
mu lo si oja,
se
N00 000000011,
bé si ni nwon yio si ma le ra nkan si ni oja.
4Bi a ba ti le ko awon oja lo si ilu okére to, béni ao si le ma
ri awon oja ilu okére ra to ninu awon ile ita’ja.
——eEeEeE—E—e———— SS SSS SS SSS =
Awon nkan rira yio po to, owo yio si wa lati fi ra won.
5Ise Ijoba ni lati ri i wipe awon ohun Ogbin jade ninu
B _AWON
TINQBA ~~ ALASOWOPQ
lo
le ste-ise o si nran awon agbe
f Ww Vi
MMMM WW
Die ninu ona ti Ijoba ngba fi se eyi ni a fi han ninu oju-iwe
6daradara.
<
ILE ISE AGBE ITOJU AWON
ERANKO
YuuY
Seth
ti o wa ni iwaju:A nri awon igi ti o nso eso daradara, a nsa won jo, nwon
si npo si i.
roy
WGWy
_
ey
VOY
Awon igi ti o dara wonyi (Kdko, ope, orombo) ati awon eso
ti o dara (owd, iresi, eré, agbado) ni a npin kakiri fun
awon agbe.
8Ijoba nfun agbe ni omo akuko adie ti o daraju. Awon omo
won ntobi, nwon si nye eyin ti o tobi.
wt Seer
| wet CoCS@®
O si ti tun mu awon malu ti o dara ju tiwa wa. Awon
wonyi si nwa pelu awon malu tiwa ati awon omo won.
oP” per
Lenalss
[/
Nwon o fun agbe ni eran t’o dara fun sisin ati fun ise agbe.
Y)Ijoba ti ri ona iwosan ati bi arun ko fi ni le ran awon eranko
ati igi inu oko.
O ti se ise yi lori artin korikori.
O si nfi han awon agbe nisisiyi bi a ti se le da arun yi duro.
10Orisirisi iyepe ile ni o wa.
Ijoba se iwadi nipa ohun eso ti a le gbin lori orisi awon ile
wonyi, o si ngba awon agbe ni imoran nipa ré.
tlAwon ile ti nwon nro ni ilu yi ima nkere ati pe apa kan ni
~ ~ e e e 8 ° e
nwon ima nro lékan. O nira lati tun ise ogbin se si ona ti
isisiyi.
Ijoba nsi awon egbe agbé
lori nibiti nwon le lo eto
ida’ko titun.
VW Ww WY yy Vv
V7 Vw yy
Wy
WW Wy
ww
piace: sf
O si tun nwa ona bi nwon ti se le lo ero agbe daradara.
12Lilo ero agbe yio jeki agbe ri nkan ogbin si i.
a r)
Sugbon ninu ohun ogbin ti o nri sii yi ni o ma fi san owo ero
ati wipe nipa ona ti a Ia sile yi nikan ni nwon le fi lo awon
ero agbé yi fun anfani agbé.
13Iwonyi ni die ninu ona miran ti Ijoba ngba fi ran awon
agbe lowo.
O si nfi han awon agbé ona ti nwon le fi jeki nkan ogbin
won dara si i.
147 SS °
A nya awon agbe I’owo lati ro ile si i
e
ni ona ti o dara.
SU VM OY
Vw ww
Nwon si le da owo yi pada lati inu opo owo ti o nwole fun
won.
15: oe S
Ijoba si tun da ile éro sile fun awon ohun Ogbin.
* .
ERO EPO
ERO ROBA
Béni a ri i pe a le gbin nkan ti o dara pupo fun tita si ilu
okére, idera a si le wa ni ile wa.
16Technical production by Buffalo Books Limited
Printed in Great Britain by Purnell and Sons, Ltd., Paulton (Somerset) and London